Awo Training Part 2
Part of the esoteric function of Ifa is to support and sustain the
health, fertility and prosperity of the community through the continuous
recitation of oriki asking for the protection and blessing of Spirit. This is
done on a daily at the personal shrine of the awo. The cycle as taught to
me by my elders involves the invocation of Ela every four days. Every
sixteen days Egbe Ifa meets to do collective chanting and divination.
Every ninety-one days the Egbe does chanting and divination to bring
good fortune to the new season. In addition the Egbe does chanting and
divination in preparation for the performance of annual festivals and
public ritual.
There is a tendency in the West to base ritual work on a seven day
cycle. The seven day cycle is based on the Julian calendar which was
created in the middle ages to deliberately alienate people from the
natural cycles of earth energy which is aligned with a four day internal
clock.
The cycle and associated prayers in this book are presented as an
example of the personal and collective chanting done in Ifa. This cycle
has a wide range of variation and remains in a constant state of growth
based on influence by Spirit. The use of this cycle is a tool for
maintaining a fluid and easily accessible link with the Invisible Forces of
Creation. It is the foundation of Ifa spiritual technology and an essential
element in the process of personal and collective growth.
Ire
Awo Falokun Fatunmbi
Egbe Ifa Ogundi Ode Remo
DAILY CYCLE
M orning Greeting to If a
ORIKI ORUNMILA
Olodumare, mo ji loni. Mo wo'gun merin aye. Igun
'kini, igun'keji, igun'keta, igun'kerin Olojo oni.
Gbogbo ire gbaa tioba wa nile aye. Wa fun mi ni temi.
T'aya - t 'omo t'egbe - t - ogba, wa fi yiye wa. Ki of
f ona han wa. Wa fi eni - eleni se temi. Alaye o alaye
o. Afuyegegege mesegbe. Alujonu eniyan ti nf owo ko
le. A ni kosi igi meji ninu igbo bi obi. Eyiti o ba ya'ko
a ya abidun - dun - dun -dim. Alaye o, alaye o. Ifa wa
gbo temi. Esu wa gbo temi. Jeki eni ye mi. Jeki eni
ye mi. Jeki eni ye mi. Ki ola san mi t'aya t'omo t'ibi
t'ire lo nrin papo ni 'ile aye. Wa jeki aye mi. Kioye mi.
Ase.
FOUR DAY CYCLE
Personal A lig n me n t with E la
ORIKI EGUN
Egungun kiki egungun. Egun iku ranran fe awo ku
opipi. O da so bo fun le wo, Egun iku bata bangoegun
de. Bi aba f atori na le egun a se de. Ase.
ORIKI ORI
Ori san mi. Ori san mi. Ori san igede. Ori san igede.
Ori otan san mi ki nni owo lowo. Ori otan san mi ki
nbimo le mio. Ori oto san mi ki nni aya. Ori oto san
mi ki nkole mole. Ori san mi o. Ori san mi o. On san
mi o. Oloma ajiki, iwa ni mope. Ase.
ORIKI ESU odArA
Esu, Esu Odara, Esu, lanlu ogirioko. Okunrin ori ita,
a jo langa langa lalu. A rin lanja lanja lalu. Ode ibi ija
de mole. Ija ni otaru ba d'ele ife. To fi de omo won.
Oro Esu, to to to akoni. Ao fi ida re lale. Esu, ma se
mi o. Esu, ma se mi o. Esu, ma se mi o. Omo
elomiran ni ko lo se. Pa ado asubi da. No ado asure
si wa. Ase.
ORIKI OSOOSI
Olog arare, agbani nijo to burn, Orisa ipapo adun,
koko ma panige, Ode olorore, Obalogara bata ma ro.
Ase.
ORIKI OGUN
Ogun Awo, Onile kangun kangun Orun. O lomi nil f
eje we olaso nle fi. Imp kimo'bora, egbe lehin a nle a
benbe olobe. Ase.
ORIKI ORUNMILA
Orunmila, ajomisanra, Agbonniregun , ibi keji
Olodumare, Elerin - ipin, Omo ope kan ti ns pro dogi
dogi, ara Ado, ara Ewi, ara Igbajo, ara Iresi, ara Ik ole,
ara Igeti, ara oke Itase, ara iwonran ibi ojumo ti nmo
waiye, akoko Olokun, pro ajo epo ma pon, olago lagi
okunrin ti nmu ara ogidan le, o ba iku ja gba omo e si
le, Odudu ti ndu ori emere, o tun ori ti ko sunwon se,
Orunmila ajiki, Orunmila ajike, Orunmila aji fi pro
rere lo. Ase.
ORIKl ELA
Ifa ro wa o. Ela ro wa o o. Bi 6 n be lapa okun. Ko ro
moo bp. Bi 6 n be ni wanran oojumo. Ase.
DARIJI
Orunmila mo pe, Orunmila mo pe, Orunmila mo pe.
Ifa mo pe, Ifa mo pe, Ifa mo pe. Oduduwa mo pe,
Oduduwa mo pe, Oduduwa mo pe. Igi nla subu
wonakankan d'etu. Orunmila ni o di adariji. Mo ni o
di adariji. O ni bi Oya ba pa ni tan. A ki i, a sa a, a f
'ake eran fun u. A dariji o ni bi Sango ba pa ni tan. A
ki i, a sa, a f agbo fun u. A dariji, o ni bi Ogun ba pa
ni tan. A dariji, Oduduwa dariji wa bi a ti ndariji
awon ti o se wa. Ase.
ORIKl IFA
Orunmila Eleri - ipin ibikeji Olodumare. A - je - je -
ogun obiriti - a - p'ijo - iku sa. Oluwa mi amoimotan -
a ko mo o tan ko se. A ba mo o tan iba se ke. Oluwa
mi Olowa aiyere omo Elesin He - Oyin. Omp ol'ope
kan t'o s'an an dogi - dogi. Oluwa mi opoki a - mu -
ide - s'oju ekan ko je k'ehun hora asaka - saka akun.
Omo Os o - ginni t apa ti ni - ewu nini. Omo Os o pa'de
mowo pa'de mese o mbere at epa oje. Oluwa mi igbo
omo iyan birikiti inu odo. Omo igba ti ns ’ope jiajia.
Iku dudu at ewo Oro aj 'epo ma pon. Agiri ile - ilobon
a - b'Olowu diwere ma ran. Oluwa mi a - to - iba -
jaiye Oro a - b'iku j'igbo. Oluwa mi Ajiki ogege a -
gb'aiye - gun. Odudu ti idu ori emere o tun ori ti ko
sain se. Omo el'ejo ti nrin mirin - mirin lori ewe.
Omo arin ti irin ode - owo saka - saka. Orunmila a
born, Orunmila a boye, Orunmila a bosise. Ase.
OLODUMARE
Iba Olodumare, Oba Ajiki ajige. Ogege Agbakiyegun.
Okitibiri Oba ti nap ojo iku da. Atere k'aiye,
Awusikatu, Oba a joko birikitikale, Alaburkuke
Ajimukutuwe, Ogiribajigbo, Oba ti o fi imole se aso
bora, Oludare ati Oluforigi, Adimula, Olofin aiye ati
Orun. A fun wen ake wen, Owenwen ake bi ala. Alate
ajipa Olofa pro Oba a dake dajo. Awosu sekan. Oba
ajuwape alaba alase lori ohun gbogbo. Araba nla ti
nmi igbo kijikiji. Oyigiyigi Oba akiku ati Oba nigbo,
Oba atenile forigbeji, Awamaridi Olugbhun mimo to
Orun. Ela funfun gbo o Oba toto bi aro, pamupamu
digijigi ekun awon aseke. Awimayehun Olu ipa Oba
Airi. Arinu rode Olumoran okan. Abowo gbogbogbo ti
yo omo re. Ninu ogin aiye ati Orun. Iba to - to - to.
Ase.
16 DAY CYCLE - EGBE IFA
C ollective P rayers
ADURA ORUNMILA OLUWA MI AJIKI
* C lap three times in front of Ifa
Ila ji Orunmila. (Ila ji Orunmila.)
Ila ji Orunmila. (Ila ji Orunmila.)
Ila ji Orunmila. (Ila ji Orunmila.)
Mo ji mo ki atola. (Ase.)
Mo ki asula. (Ase.)
Mo ki asurunenene . (Ase.)
Ina ku - ku - ku l'ahere. (Ase.)
Enia ku - ku - ku l'aba. (Ase.)
Adifa fun ogojo l'imp ogbpjo. (Ase.)
O ni'ti awo yo ogbpjo. (Ase.)
Ti awo yo ogbpjo. (Ase.)
Nje Oluwa mi ma jeki tire yo o.
Ikunle and rub hands together in front of If a
*
Awo ajiki l'awo ajiki. (Awo ajiki l’awo ajiki.)
Awo ajiki l'awo ajiki. (Awo ajiki l’awo ajiki.)
Awo ajiki l'a ipe awo aja - ale - gbun. (Ase.)
A da a awon meta nlo bo ori - elu. (Ase.)
Ori - elu ko gb'ebo lowo won. (Ase.)
Awo ajiki l'awo ajiki. (Awo ajiki l’awo ajiki.)
Awo ajiki l'awo ajiki. (Awo ajiki l’awo ajiki.)
Awo ajiki l'a ipe awo aja - ale gbun. (Ase.)
A da fun iki t'o on yio bp ori - elu. (Ase.)
Yio gba ibo lowo on. (Ase.)
Iki ji o wewo fini o wewe fini. (Ase.)
O wa imu obi o na a si ori - elu. (Ase.)
Ori - elu gba lowo re. (Ase.)
O ni lowo iki eleyinju ege l'a to mi ibo e. (Ase.)
Igbana ni iki m 'ekun s 'ekun igbe. (Ase.)
O m'ohun s'ohun yere nkorin wipe. (Ase.)
Gb'obi pa o! (Awo aye!)
Gb'obi pa o! (Awo aye!) Ase.
ORIKI ORUNMILA
Orunmila elerin-ipin, Aje ju gun, Ibi keji Olodumare
akoko Olokun, ajao ikoto ara Ado, ara Ewi, ara oke
It ase, ara ojumo, ibiti ojo ti nmo, waiye ara oke l'geti
okeje oje. (Ase.)
Erin fon olagilagi okunrin, ti nmu ara ogidan le,
alakete pennepe, pari ipin, oloto kan to ku l'aiye,
Oba iku ja gba omo re sile, odudu ti ndu or emere, ma
ba fo otun ori ti, ko sun won se. (Ase.)
KIKI IFA
Eye kan an fo lere mi, lere mi, o f 'apa otun bale, o re
gbpngbongbon bi oko. (Ire.)
Eye kan an ba lere mi, lere mi, o f apa otun bale, o re
gbongbpngbon bi ada. (Ire.)
Bi alaworo - Orisa ba ji, a fada Orisa no'le, a ni "Orisa,
ejitabeoji!" (Ire.)
Baba lo sun ni ko ji. (Ire.)
Jiji ni ki o ji o, mo - Kun - Otan l'Eri. (Ire.)
Jiji ni ki o ji, mosun nile Ilawe. (Ire.)
Jiji ni ki o ji o, ojiji alaoo nini. (Ire.)
Baba ni bi oun ko ba ji nke? (Ire.)
Mo: "bi isekuse ba se gbogbo eye oko ni ji." (Ire.)
Bi Ojiji ba parada lodo. (Ire.)
Gbogbo eja omi ni ji. (Ire.)
Baba ni bi oun ba ji bi oun ko ba koju nko? (Ire.)
Mo ni: "asuigbo ki koju si'ibo." (Ire.)
Asuodan ki koyin s'ona. (Ire.)
Bi ewe otiti ba tu, oju Olodumare ni nkojusi? (Ire.)
Baba ni bi oun ba ji bi oun ko rerin nko? (Ire.)
Mo ni: "rerin, mo ni erin la rin f ona oti." (Ire.)
Erin lagbara nrin k' Olodo Iona. (Ire.)
Baba ni; "bi oun ba rerin, bi ko tan ninu oun nko?"
(Ire.)
Mo ni: "bi a se ba mu omi, a tan nnu ase." (Ire.)
Bi igere ba mu omi, a tan nnu igere. (Ire.)
B'alaworo - Osa ba maa soro lodun. (Ire.)
Bi o ba ranse p'Onigbajamo, a fa irun ori re tan
porogodo. (Ire.)
Odun ko jeran mimi. (Ire.)
Ija ko jeran ikase. (Ire.)
O tori Olalekun, Ominikun, Atatabiakun, erin - ko -
yipada - kun? (Ire.)
Abata kunkunkun ko tan lehin okun. (Ire.)
Amonato, amonasegaara - de - Fe, Gburu agba. (Ire.)
"Ilu meji gedegede Ilu gedegede lo tegun - n'lu Oba lo
teyin erin n fpn" A daa f Orunmila, Baba ns'awo r'ode
Ominikun, ni ibi ti gbogbo won ngbe se'fa. (Hein.)
Ifa bi mo ba se e, ki o mase fi'binu gb'eku.
(Fifereji ni o fereji, bi ara ode Ominikun.)
Ifa bi mo ba se e, ki o mase fi'binu gb'eja.
(Fifereji ni o fereji, bi ara ode Ominikun.)
Ifa bi mo ba se o, ki o mase fi'binu gb'eye.
(Fifereji ni o fereji, bi ara ode Ominikun.)
Ifa bi mo ba se e, ki o mase fi'ran gb'eran.
(Fifereji ni o fereji, bi ara ode Ominikun.)
Ifa bi mo ba se e, ki o mase fi iran gba ototo ohun.
(Fifereji ni o fereji, bi ara ode Ominikun.)
Bi a ba jeko a darij'ewe. Ferejin mi o, bi ara ode
Ominikun. (Hein.)
Oba Alade Feejin mi, Oba Alaferejin. (Hein.)
Ase.
Eriwo ya. (Agbo ato.)
ORIKI ELA
Ela omo osin. (Ase.)
Ela Omo Oyigiyigi ota omi. (Ase.)
Awa di oyigiyigi. (Ase.)
A ki o ku wa. (Ase.)
Ela ro a ki o ku mo, okiribiti. (Ela ro.)
Ela ro. (Sokale)
Orunko Ifa. (Ela ro.)
Entiti ngba ni l'a. (Ase.)
Nwon se ebo Ela fun mi. (Ire.)
Ko t'ina, ko to ro. (Ela ro.)
Beni on ni gba ni la n'lf e, Oba - a - mola. (Ase.)
Ela, Omo Osin mo wari o! (Ela ro.)
Ela meji, mo wari o. (Ela ro.)
Ela mo yin boru, Ela mo yin boye. Ela mo yin bosise.
(Agbo ato.)
Ela poke . (Ela ro . )
Eni esi so wa soro odun. (Ase.)
Odun ko wo wa sodun. (Ase.)
Iroko oko. (Iroko oko.)
Iroko oko. (Iroko oko.)
Iroko oko. (Iroko oko.)
Odun oni si ko. (Ase.)
Ela poke.
Ela ro. (Sokale)
Ela ro. (Sokale)
Ela ro, ko wa gbu're. (Sokale)
Ela takun wa o. (Ase.)
Eti ire re. (Ela takun ko wa gbu ’re.)
Enu ire re. (Ela takun ko wa gbu're.)
Oju ire re. (Ela takun ko wa gbu ’re.)
Ela ma dawo aje waro. (Ase.)
Ela ma d'ese aje waro. (Ase.)
Atikan Sikun ki oni ikere yo ikere. (Ase.)
Ipenpe'ju ni si'lekun fun ekun agada ni si'ekun fun eje.
(Ase.)
Ogunda'sa, iwo ni o nsilekun fun Ejerindilogun
Inmmole. (Ase.)
Ela panumo panumo. (Ase.)
Ela panuba panuba. (Ase.)
Ayan ile ni awo egbe ile, ekolo rogpdo ni awo ominile.
(Ase.)
Eriwo lo sorun ko do mo. (Ase.)
O ni ki a ke si Odi awo Odi. (Ase.)
O ni ki a ke si Ero awo Ero. (Ase.)
O ni ki a ke si Egun o susu abaya babamba. (Ase.)
A ke si Ero awo Ero, ke si Egun o susu abaya babamba
a ni eriwo lo si Orun ko de mo, won ni ki Ela ro ibale.
(Ase.)
Ela ni on ko ri ibi ti on yio ro si o ni iwaju on egun.
(Ase.)
Ey in on osusu agbede'nji on egun osusu, awo fa ma je
ki'iwaju Ela gun mori on tolu. (Ase.)
Orunmila ma je ki eyin Ela gun mosi Olokarembe
Orunmila ma je ki agbedemeje la gun osusu. (Ase.)
Ela ro. (Sokale)
Ifa ko je ki iwaju re se dundun more on tolu. (Ase.)
Ela ro. (Sokale)
Ifa ko je ki eyin re se wprpwo
Ela ro. (Sokale)
Ela ni 'waju o di O dun dun.
Ela ro. (Sokale)
Ela ni eyin o di Tete.
Ela ro. (Sokale)
Ela ni agbedemeji o di wprpwo. (Ase.)
ALAFIA OPON
Iwaju opon o gbo o. (Ire.)
Eyin opon o gbo. (Ire.)
Olumu otun. (Ire.)
Olokanran osi. (Ire.)
Aarin opon ita Oran. (Ase.)
ORIKI IKIN
Orunmila o gbo o. (Ire.)
Orunmila iwo 'awo. (Ire.)
Oun awo. (Ire.)
Owo yi awo. (Ire.)
Emi nikansoso l'ogberi. (Ase.)
A ki'fa agba Merindinlogun sile k'asina. (Ase.)
Eleri Ipin f ona han mi. (Ase.)
ORIKI IFA
Ifa ji - o Orunmila. (Ase.)
Bi olo 1 - oko, ki o wa le o. (Ase.)
Bi olo 1 - lodo, ki o wa le - o. (Ase.)
Bi olo 1 - ode, ki o wa le - o.
* P lace the bowl of ikin on the ground to the left
Mo fi ese re te - le bayi. (Ase.)
Mo fi ese re te ori eni bayi, mo gbe o ka 1 - ori eni ki o
le gbe mi ka 1 - ori eni titi lai. (Ase.)
* P lace the bowl on the tray
Mo gbe o ka 1 - ori opon Ifa ki o le gbe mi ka
1 - ori opon Ifa titi lai. (Ase.)
* D raw a line around the bowl clockwise
Mo kg - le yi o ka ki o le kg - le, yi me ka ki o le jeki
gmg yi mi ka ki o le jeki owo yi mi ka. (Ase.)
* E rase the line with a feather
Orin; Iba se o, mo juba e.
* S prinkle iyerosun on the floor
lie mo juba. (Iba se.)
* M ark a line from the center to the top of the tray
Mo la gna fun tororo ki o le la ona fun mi tororo ki o
le jeki gmg to gna yi wa s - gdg mi ki o le jeki owo tg
gna yi wa s - gdg mi. (Ase.)
* Stir the Iyerosun on the floor with a feather
Mo se il e bayi. (Ase.)
* Stir the iyerosun tray
Mo se gpgn bayi. (Ase.)
* T ap on the tray
A - gun se - o a - gun se. Bi akoko g - ori igi a se, a -
gun se - o, a - gun se. (Ase.)
Bi agbe ji a ma se, a - gun se - o, a - gun se. (Ase.)
Bi aluko ji a ma se, a - gun se - o, a - gun se. (Ase.)
Iba se (Name of Orisha ) Oba aiye ati Oba Orun iba yin
o. (Mo juba.)
Orunmila boru, Orunmila boye, Orunmila bosise.
*
C lap hands three times
Adupe - o. (A dupe.)
* C ount out sixteen Ikin from the bowl
A tun ka li asiwere ika owo re. (Ase.)
Iba Akoda. (Mo juba.)
Iba Aseda. (Mo juba.)
Iba Oluwo. (Mo juba.)
Iba Ojugbona. (Mo juba.)
Iba a ko ni li - fa. (Mo juba.)
Iba a te ni 1 - ere. (Mo juba.)
Iba a ko bayi. (Mo juba.)
Iba a te bayi. (Mo juba.)
Iba gbodipete. (Mo juba.)
Iba kukubole. (Mo juba.)
Iba okuta. (Mo juba.)
Iba loko. (Mo juba.)
Iba lodo. (Mo juba.)
Oro kan so ko si awo n - ile pro kan so ko si agba n -
ile. (Ase.)
ORIN IKIN
Call; Ejiogbe a buru a boye akala o.
Response; A akala, a akala o.
Call; Oyeku meji a buru a boye akala o.
Response; A akala, a akala o.
IFAIYABLE
S'otito s'ododo; soore ma s'eka. Otito a b ona tooro.
(Ase.)
Osika a b ona gbara, s'otito s'ododo; s'otito s'ododo;
eni s'otito ni'male ngbe. (Ase.)
Iwori - tejumo - ohun - ti - i - se - 'nl bi o ba te 'fa ki o
tun iye inu re te. (Ase.)
Awo, ma fi eja igba gun ope. (Ase.)
Awo ma fi aimowe wo omi, awo, ma ibinu yo Obe,
awo, ma fi ma san bante awo. (Ase.)
OSUMARE
Osumare a gbe Orun li apa ira o pon iyun pon nana, a
pupo bi Orun oko Ijoko dudu oju e a fi wo ran. (Ase.)
OLODUMARE
Iba Olodumare, Oba Ajiki ajige. (Ase.)
Ogege Agbakiyegun. (Ase.)
Okitibiri Oba ti nap ojo iku da. (Ase.)
Atere k'aiye, Awusikatu, Oba a joko birikitikale,
Alaburkuke Ajimukutuwe, Ogiribajigbo, Oba ti o fi
imole se aso bora, Oludare ati Oluforigi, Adimula,
Olofin aiye ati Oran. (Ase.)
A fun wen ake wen, Owenwen ake bi ala. (Ase.)
Alate ajipa Olofa pro Oba a dake dajo.Awosu sekan.
(Ase.)
Oba ajuwape alaba alase lori ohun gbogbo. (Ase.)
Araba nla ti nmi igbo kijikiji. (Ase.)
Oyigiyigi Oba akiku ati Oba nigbo, Oba atenile
forigbeji, Awamaridi Olugbhun mimo to Orun. (Ase.)
Ela funfun gbo o Oba to to bi aro, pamupamu digijigi
ekun awon aseke. (Ase.)
Awimayehun Olu ipa Oba Airi. Arinu rode Olumoran
okan. (Ase.)
Abowo gbogbogbo ti yo omo re. Ninu ogin aiye ati
Orun. (Ase.)
Iba to - to - to. Ase.
91 DAY CYCLE
Invocation for the Seasons
ADURA ORUNMILA OLUWA MI AJIKI
* Clap three times in front of Ifa
Ila ji Orunmila. (Ila ji Orunmila.)
Ila ji Orunmila. (Ila ji Orunmila.)
Ila ji Orunmila. (Ila ji Orunmila.)
Mo ji mo ki atola. (Ase.)
Mo ki asula. (Ase.)
Mo ki asyurunenene. (Ase.)
Ina ku - ku - ku 1 'ahere. (Ase.)
Enia ku - ku - ku 1 'aba. (Ase.)
Adifa fun ogojo l'imp ogbojo. (Ase.)
O ni 'ti awo yo ogbojo. (Ase.)
Ti awo yo ogbojo. (Ase.)
Nje Oluwa mi ma jeki tire yo o.
* Ikunle and rub hands together in front of If a
Awo ajiki l'awo ajiki. (Awo ajiki l’awo ajiki.)
Awo ajiki l'awo ajiki. (Awo ajiki l’awo ajiki.)
Awo ajiki l'a ipe awo aja - ale - gbun. (Ase.)
A da a awon meta nlo bo ori - elu. (Ase.)
Ori - elu ko gb'ebo lowo won. (Ase.)
Awo ajiki l'awo ajiki. (Awo ajiki l’awo ajiki.)
Awo ajiki l'awo ajiki. (Awo ajiki l’awo ajiki.)
Awo ajiki l'a ipe awo aja - ale gbun. (Ase.)
A da fun iki t'o on yio bp ori - elu. (Ase.)
Yio gba ibo 1 owo on. (Ase.)
Iki ji o wewo fini o wewe fini. (Ase.)
O wa imu obi o na a si ori - elu. (Ase.)
Ori - elu gba lowo re. (Ase.)
O ni lowo iki eleyinju ege l'a to mi ibo e. (Ase.)
Igbana ni iki m'ekun s'ekun igbe. (Ase.)
O m'ohun s'ohun yere nkorin wipe. (Ase.)
Gb'obi pa o! (Awo aye!)
Gb'obi pa o! (Awo aye!) Ase.
IBA'SE
Op e ni fun Olorun. (Ase.)
Iba Olodumare, Oba ajiki. Mo ji loni. Mo wo'gun
merin aye . (Mo j uba . )
Iba Elawori. Agbegi lere, la' fin ewu l'ado, eniti
Olodumare ko pa'jo eda, Omo Oluworiogbo. (Mo juba.)
iba'se ila Oorun. (Mo juba.)
iba'se iwo Oorun. (Mo juba.)
Iba'se Ariwa. (Mo juba.)
Iba'se Guusu. (Mo juba.)
iba Oba igbalye. (Mo juba.)
Iba Orun Oke. (Mo juba.)
iba Atiwo Orun. (Mo juba.)
iba Olokun a - soro - day 6 . (Mo juba.)
iba afefelegelege awo isalu - aye. (Mo juba.)
iba Ogege, Oba. (Mo juba.)
iba titi aiye 16 gbere. (Mo juba.)
iba Oba awon Oba. (Mo juba.)
iba Okiti biri, Oba ti np 'ojo iku da. (Mo juba.)
iba ate - ika eni Olodumare. (Mo juba.)
iba Odemu demu kete a lenu ma fohun.
iba'se awon iku emese Orun. (Mo juba.)
Iba Ori. (Mo juba.)
iba Ori inu. (Mo juba.)
iba Iponri ti 6 wa' l'Orun. (Mo juba.)
iba Kori. (Mo juba.)
iba Ajala - Mo pin. (Mo juba.)
iba Odo - Aro, ati Odo - Eje. (Mo juba.)
Orun Ori nile, e 66 jisdn, e 66 jabo oun ti e ri. (Mo
juba.)
iba Esu Odara, Okunrin ori ita, ara Oke itase, ao fi ida
re lale. (Mo juba.)
iba Osoosi ode mat a. (Mo juba.)
iba Ogun awo, Onile kangu - kangu Orun. (Mo juba.)
iba Obatala, Orisa Ose re Igbo. Oni kutukutu awo
owuro, Iku ike, Oba pata - pata ti won gb'ode iranje.
(Mo juba.)
iba Yemoja Olugbe - rere. (Mo juba.)
iba Osun oloriya igun arewa obirin. (Mo juba.)
iba Olukoso aira, bambi pmo arigba seg un. (Mo juba.)
iba Ajalaiye Ajalorun Oya Oluweku. (Mo juba.)
iba ibeji oro. (Mo juba.)
iba Aje - ogunguluso Olambo yeye aiye. (Mo juba.)
iba Awon iyaami, Alagogo eiswu a p'oni ma hagun.
(Mo juba.)
iba Orunmila Eleri ipin, Iku dudu ate wo. (Mo juba.)
Oro to si gbogbo ona. (Mo juba.)
Iba Awo Akoda. (Mo juba.)
Iba Awo Aseda. (Mo juba.)
iba Ojubo onome a. (Mo juba.)
Ase.
ORIKi ORUNMiLA
Orunmila, Bara Agboniregun, ad ese omilese a - mo -
ku - Ikuforiji Olijeni Oba Olofa - Asunlola nini - omo
- Oloni Olubesan. (Ase.)
Erintunde Edu Ab'ikujigbo alajogun igbo Oba - igede
para petu opitan -elufe, amoranmowe da ara re
Orunmila. (Ase.)
Iwo li o ko oyinbo l'ona odudupasa. (Ase.)
A ki igb'ogun l'ajule Orun da ara Orunmila. (Ase.)
A ki if agba Merindinlogun sile k'a sina. (Ase.)
Ma ja, ma ro Elerin Ipin ibikeji Edumare. (Ase.)
F'onahan'ni Orunmila. (Ase.)
Iburu, Iboye, Ibosise. (Ase.)
ORIKi ELA
Ela omo osin. (Ase.)
Ela Omo Oyigiyigi ota omi. (Ase.)
Awa di oyigiyigi. (Ase.)
A ki o ku wa. (Ase.)
Ela ro a ki o ku mo, okiribiti. (Ela ro.)
Ela ro. (Sokale)
Orunko Ifa. (Ela ro.)
Entiti ngba ni l'a. (Ase.)
Nwon se ebo Ela fun mi. (Ire.)
Ko t'ina, ko to ro. (Ela ro.)
Beni on ni gba ni la n'lfe, Oba - a - mola. (Ase.)
Ela, Omo Osin mo wari o! (Ela ro.)
Ela meji, mo wari o. (Ela ro.)
Ela mo yin boru, Ela mo yin boye. Ela mo yin bosise.
(Agbo ato.)
Ela poke . (Ela ro . )
Eni esi so wa soro odun. (Ase.)
Odun ko wo wa sodun. (Ase.)
Iroko oko. (Iroko oko.)
Iroko oko. (Iroko oko.)
Iroko oko. (Iroko oko.)
Odun oni si ko. (Ase.)
Ela poke. (Ase.)
Ela ro. (Sokale)
Ela ro. (Sokale)
Ela ro, ko wa gbu're. (Sokale)
Ela takun wa o. (Ase.)
Eti ire re. (Ela takun ko wa gbu ’re.)
Enu ire re. (Ela takun ko wa gbu're.)
Oju ire re. (Ela takun ko wa gbu ’re.)
Ela ma dawo aje waro. (Ase.)
Ela ma d'ese aje waro. (Ase.)
Atikan Sikun ki oni ikere yo ikere. (Ase.)
Ipenpe'ju ni si'lekun fun ekun agada ni si'ekun fun eje.
(Ase.)
Ogunda'sa, iwo ni o nsilekun fun Ejerindilogun
Irunmole. (Ase.)
Ela panumo panump. (Ase.)
Ela panuba panuba. (Ase.)
Ayan ile ni awo egbe ile, ekolo rogpdo ni awo ominile.
(Ase.)
Eriwo lo sorun ko do mo. (Ase.)
O ni ki a ke si Odi awo Odi. (Ase.)
O ni ki a ke si Ero awo Ero. (Ase.)
O ni ki a ke si Egun osusu abaya babamba. (Ase.)
A ke si Ero awo Ero, ke si Egun o susu abaya babamba
a ni eriwo lo si Orun ko de mo, won ni ki Ela ro ibale.
(Ase.)
Ela ni on ko ri ibi ti on yio ro si o ni iwaju on egun.
(Ase.)
Ey in on osusu agbede'nji on egun osusu, awo fa ma je
ki'iwaju Ela gun mori on tolu. (Ase.)
Orunmila ma je ki eyin Ela gun mosi Olokarembe
Orunmila ma je ki agbedemeje la gun osusu. (Ase.)
Ela ro. (Sokale)
Ifa ko je ki iwaju re se dundun more on tolu.
Ela ro. (Sokale)
Ifa ko je ki eyin re se worowo
Ela ro. (Sokale)
Ela ni 'waju o di Odun dun.
Ela ro. (Sokale)
Ela ni eyin o di Tete.
Ela ro. (Sokale)
Ela ni agbedemeji o di worowo. (Ase.)
ORIKI EJIOGBE
Ejiogbe, Ejiogbe, Ejiogbe. (Leemeta.)
Mo be yin, kiegbe mi ki'mi niyi, ki e egbe mi ki'mi
n'ola, ifakifa kiini'yi koja Ejiogbe. (Ire.)
Ejiogbe ni Baba - gbogbo won. (Ire.)
Ki gbogbo eniyan kaakiri agbaye gbarajo, kiwon maa
gbe 'mi n'ija, kiegbe mi leke ota. (Ire.)
Ki nle 'ke odi. (Ire.)
Kiemaa gbe'mi n'ija kiemaa gbe mi leke isoro lojo
gbogbo ni gbogbo ojo aye mi. (Ire.)
Kiemaa gbe ire ko mi nigbabogbo tabi kiemaagbe fun
mi. (Ase.)
ORIKI OYEKU MEJI
Oveku Meji, Oveku Meji, Ov eku Meji. (Leemeta.)
Mo be yin, bi iku ba sunmo itosi ki e bami ye ojo iku
fun. (Ire.)
Si ehin Ogun tabi ogorun odun, tabi bi iku ba nbo kie
bami yee si ehin ogofa. (Ire.)
Odun tiatibi mi sinu aye ki e bami ye ojo iku fun ara
mi ati aw on omo mi ti mo bi. (Ire.)
Kiamaku ni kekere, kiamaku iku ina, kiamaku iku
oro, kiamaku iku ejo, Kiamaku sinu omi. (Ase.)
ORIKI IWORI MEJI
Iwori Meji, Iwori Meji, Iwori Meji. (Leemeta.)
Mo be yin ki a f f oju re wo mi, ki awon omo araye lee
maa fi oju rere wo mi. (Ire.)
Ki e ma jeki nsaisan ki nsegun odi ki nrehin pta.
(Ire.)
Ki e ma jeki awon iyawo mi ya'gan, takotabo ope
kiiya-agan. Iwori Meji. (Ase.)
ORIKI ODI MEJI
Odi Meji, Odi Meji, Odi Meji. (Leemeta.)
Mo be yin, ki e bami di ona ofo, ki e bami di odo ofo,
ki e bami di ona ejo, ki e bami di ona ibi, ki e bami di
ona Esu. (Ire.)
Ni nri'di joko pe nile aye. Kiema jeki nba won ku -
Iku ajoku. (Ire.)
Okan ewon kiike. (Ire.)
Ki e se - Odi agbara yi mi ka, ki owo mi ka'pa omo
araye bi omo Odi tiika'lu. (Ase.)
ORIKI IROSUN MEJI
Irosun Meji, Irosun Meji, Irosun Meji. (Leemeta.)
Mo be yin, ki e jeki awon omo - araye gburo, mi pe mo
l'owo lowo, pe mo niyi, pe mo n 'ola, pe mo bimo rere
ati beebee. (Ire.)
Ki e jeki won gbo iro mi kaakiri agbaye, Irosun Meji.
(Ase.)
ORIKI OWONRIN MEJI
Owonrin Meji, Owonrin Meji, Owonrin Meji. (Leemeta.)
Mo be yin, ki eso ibi de rere fun mi ni gbogbo ojo aye
mi, ki emi - re s' owo, ki emi mi gun ki ara mi kiole, ki
nma ri ayipada di buburu lojp aye mi ati beebee. (Ire.)
Owonrin Meji. (Ase.)
ORIKl OBARAMEJI
Obara Meji, Obara Meji, Obara Meji. (Leemeta.)
Mo be yin, ki e si'na aje fun me, ki awon omo araye
wa maa bami, ra oja ti mo ba niita warawara, ipeku
Orun e pehinda 1' gdo mi. (Ire.)
Ibara Meji de at beebee. (Ase.)
ORIKl OKANRAN MEJI
Okanran Meji, Okanran Meji, Okanran Meji. (Leemeta.)
Mo be yin, ki e jeki oran ibanje maa kan gbogbo awon
ti, o ndaruko mi ni ibi ti won nsep e so mi, ti won
nsoro buburu si oruko mi, awon ti nbu mi, ti won nlu
mi ti won, ngb'ero buburu si mi. (Ire.)
Okanran Meji, Okanran Meji, Okanran Meji, kiesi
ilekun ori rere fun mi ati beebee. (Ase.)
ORIKl OGUNDA MEJI
Ogunda Meji, Ogunda Meji, Ogunda Meji. (Leemeta.)
Mo be yin, kiedai ni'de Arun Ilu ejo, egbese ati
beebee, ki e d a'ri ire owo, ise pro omo ola ola
emigigun, aralile ati beebee s'odo mi. (Ire.)
Ki e da mi ni abiyamo tiyoo bimo rere ti won, yoo
gb'ehin si - sinu aye ati beebee. (Ire.)
Ogunda Meji. (Ase.)
ORIKl OSA MEJI
Osa Meji, Osa Meji, Osa Meji. (Leemeta.)
Mo be yin, ki e jeki ndi arisa-ina, akotagiri ejo fun
awon ota, kieso mi di pupo gun rere, ki'mi r'pwo san
owo ori, kimi r'pwo san awin Orun mi ati beebee.
(Ire.)
Osa Meji. (Ase.)
ORIKI IKA MEJI
Ika Meji, Ika Meji, Ika Meji. (Leemeta.)
Mo be yin, ki e ka ibi kuro Iona fun mi lode aye. (Ire.)
Ki e bami ka'wo Iku. (Ire.)
Arun ejo ofo ofo efun edi apeta oso. (Ire.)
Aje at awon oloogun buburu gbogbo. (Ire.)
Ika Meji. (Ase.)
ORIKI OTURUPON MEJI
Oturupon Meji, Oturupon Meji, Oturupon Meji.
(Leemeta.)
Mo be yin, ki e jeki Iyawo mi r'omo gbe pon, ki o
r'omo gbe sire, ki e jeki oruko mi han si rere, ki ipa
mi laye ma parun. (Ire.)
Omi kiiba'le kiomani'pa, ki 'mi ni'pa re laye ati
beebee. (Ire.)
Oturupon Meji. (Ase.)
ORIKI OTURA MEJI
Otura Meji, Otura Meji, Otura Meji. (Leemeta.)
Mo be yin, ki e bami tu imo o so, ki e ba mi tumo Aje,
ki e bami tumo awon amoniseni, imo awon
afaimoniseni ati imo awon asenibanidaro, ti nro ibi si
mi ka. (Ire.)
Otura Meji. (Ase.)
ORIKI IRETE MEJI
Irete Meji, Irete Meji, Irete Meji. (Leemeta.)
Mo be yin, ki e bami te awon ota mi. (Ire.)
Mole tagbaratagbara won ki e ma jeki nr'ibi abiku
omo. (Ire.)
Irete Meji. (Ase.)
ORIKl OSE MEJI
Ose Meji, Ose Meji, Ose Meji. (Leemeta.)
Mo be yin, ki e fun mi ni agbara, ki n seg un awon ota
mi loni ati ni gbogbo ojo aye mi, kiemaa bami fi i se
segbogbo awon eniti nwa Ifarapa ati beebee fun mi.
Ki e jeki ngbo ki nto ki npa ewu sehin. (Ire.)
Ose Meji. (Ase.)
ORIKl OFUN MEJI
Ofun Meji Oloso, Ofun Meji Olowo, Ofun Meji Olowo.
(Leemeta.)
Mo be yin, ki e fun mi lowo ati ohun rere gbogbo.
(Ire.)
Eyin li e nfun Alara lowo ki e fun emi, naa 1 owo ati
ohun rere gbogbo. (Ire.)
Eyin li e nfun Ajero lowo, ki e fun emi naa 1 owo ati
ohun rere gbogbo. (Ire.)
Eyin le e nfun Orangun He - Ila l'owo, ki e masai fun
emi naa lowo ati ohun rere gbogbo ati beebee titi lo.
(Ire.)
Ofun Meji Olowo. (Ase.)
ORUKO ESU odArA OLOPA OLODUMARE ENITI
NSO ITE MIMO - OSE TURA
Iba Esu Odara, Lalu okiri oko. (Ase.)
Agbani wa oran ba ori da. (Ase.)
Osan sokoto penpe ti nse onibode Olorun. (Ase.)
Oba ni ile ketu. (Ase.)
Alakesi emeren ajiejie mogun. (Ase.)
Atunwase ibini. (Ase.)
Elekun nsunju laroye nseje. (Ase.)
Asebidare. (Ase.)
Asare debi. (Ase.)
Elegberin ogo agongo. (Ase.)
Ogojo oni kumo ni kondoro. (Ase.)
Alamulamu bata. (Ase.)
Okunrin kukuru kukuru kukuru ti. (Ase.)
Mba won kehin oja ojo ale. (Ase.)
Okunrin dede de be Orun eba ona. (Ase.)
Iba to-to-to. Ase.
(EAST)
Awa yin O Olorun, Olu Ose at'Odun, awa yin oruko re,
ope fun O loni yi. (Ase.)
Awa n sop e fun'dasi, emi we di Odun yi awa yin O baba
wa, fun ipamo anu re. (Ase.)
Op o l'awon t'o ti sun ninu ibo ji won, awa nudupe
Baba wa fun idasi emi wa. (Ase.)
Pupo wa loni lori akete ide arun, pupo mbe ni ihamo,
sugbon 'Wo ko se wa be. (Ase.)
Ibanjue ti s'opo d'eni kiku laisin, wahala ti so opplppp
di eni ti npose. (Ase.)
S'Odun yi ni ibukun, Baba l'Orun agbaiye fi iso re tun
so wa d'opin re lailewu. (Ase.)
Iba fun Odumare Olorun wa kansoso, eni mimo aileri,
Olu Orun at 'aiye. (Ase.)
(WEST)
Olu ojo ati ose, Olu osu at'odun, Olu igbagbogbo lai,
ope fun O loni yi. (Ase.)
A dupe idasi wa di odun titun, Baba, enu wa ko gba
ope, nitori isenu ife re. (Ase.)
A! Olu, Baba l'Orun Afeni - li - afetan, Olu alafia wa,
Baba. (Ase.)
Awa yin O, a sop e a korin iyin sin O. (Ase.)
Eni - Ataiye baiye, Ala funfun gbo, mimo lailai bi aso
ala, ope temi wa doni. (Ase.)
Sugbo ninu if e re ailegbera si wa, O fi ife re mu wa di
entiti o ri odun yi. (Ase.)
S' odun yi ni rera fun wa Olu odun ati osu, fi alafia re
so wa de opin re lailewu. (Ase.)
F'opo han wa si rere, nirorun ati itunu, nibukun ati
eto, Baba ona 'waiye wa. (Ase.)
Emi yin O, Baba mi, emi ki O Ore mi, ope fun O
Oluwa apata abo mi. (Ase.)
Emi juba, mo jewo pe ko si abo bi re, mo se toto, mo
tun yin Iwo Baba t'p so mi. (Ase.)
Ko si eso t'o dabi re ni 'gun mererin aiye, tabi loke ni
Orun bi Iwo am' emi dodun.(Ase.)
Woyi esi mo dake, ate mi nmi laif ohun, mo mbe laye
b'eniku sugbon loni emi nsin. (Ase.)
Tani npani lehin re, tani nlani ju'Wo lo? (Ase.)
Iwo ni Olu Ela, a so oku d'aiye. (Ase.)
Emi yin o, Baba mi, Orun eso gbala mi, m f okan dupe
fun o, Oba - Olugbe ja mi. Gbogbo Irunmale l'Orun at
awon mimo laiye, e ba mi f orin ago yin Oba rere lai.
(Ase.)
Ifa bun Odumare, Olorun wa kansoso, eni mimo aileri,
Olu Orun at'aiye. (Ase.)
(NORTH)
Adu yin Odumare, e dupe f Olorun wa wa t'o pa wa mo
ninu ewu titi di ojo oni. (Ase.)
Awa juba a yin O, fun pamo re lori wa, fun opolopo
ewu t'o ti pa wa mo nu re. (Ase.)
Mase jek'alaigbagbo, bere Olorun awa, jowo f anu re
sowa titi dopin odun yi. (Ase.)
Pese onje ojo wa, at'aso t'ao fi bora, basiri wa Olorun,
ma jeki a rahun laiye. (Ase.)
Iba fun Odumare, Olorun wa kansoso eni mimo aileri
Olu Orun at'aiye. (Ase.)
(SOUTH)
Olorun Olodumare, Oba ti o logo, ti o si lola,
Ogiribajigbo Oba ti o fi imole bora bi aso. (Ase.)
Araba nla ti nmi igbo kijikiji, Iwo ni Olu Odun, Osu,
Ose ati Ojo, a dupe lowo re ti o fun wa ni anfani lati ri
odun yi, ni alafia ati ayo, a si be O pe bi o ti mu wa la
eyiti o koja yi ja lailawu, beni ki o keki a fi idunnu ati
alafia ri opin eyi na, se odun yi ni ohun irora, owo
rere, ati ti onto anfani, pin alafia ati ibukun re kari
onikaluku wa, pese fun awon ti ko ri i se se, awon ti
ori se, jowo mase jeki o bp lowo won, fun awon ti ko
ni omo na seku, pese fun awon ti o nta ati awon ti o
nra, dari ibukun re sodo awon onise owo, ati awon
agbe, yi li awa ntoro, ti a si mbebe lodo re, Baba
Olore Ofe, nitori Iwo Odumare li o pa lase fun
Orunmila pe, ej o niti ibi ginngin gun ewe, akan niti
ibi ikoko wo odo a difa fun emi ti nse oloja li awujo
ara, nje emi di ploja ara, bi iku ko pa emi ao se
ajodun, emi de oloja ara, se eyi fun wa, Oba alogo
lola, aniyi leye, nitori ogo oruko re, ati ola re, ti o fun
Orunmila ati Ela Awoya mimo, Olorun kan aiye
ainipekun. (Ase.)
ALAFIA OP ON
Iwaju opon o gbo o. (Ire.)
Eyin opon o gbo. (Ire.)
Olumu otun. (Ire.)
Olokanran osi. (Ire.)
Aarin opon ita Orun. (Ase.)
ORIKI IKIN
Orunmila o gbo o. (Ire.)
Orunmila iwo 'awo. (Ire.)
Oun awo. (Ire.)
Owo yi awo. (Ire.)
Emi nikansoso l'ogberi. (Ase.)
A ki'fa agba Merindinlogun sile k'asina. (Ase.)
Eleri Ipin f 'ona han mi. (Ase.)
ORIKI IFA
Ifa ji - o Orunmila. (Ase.)
Bi o lo 1 - oko, ki o wa le o. (Ase.)
Bi o lo 1 - lodo, ki o wa le - o. (Ase.)
Bi o lo 1 - ode, ki o wa le - o. (Ase.)
* P lace the bowl of ikin on the ground to the left
Mo fi ese re te - le bayi. (Ase.)
Mo fi ese re te ori eni bayi, mo gbe o ka 1-ori eni ki o
le gbe mi ka 1 - ori eni titi lai. (Ase.)
* P lace the bowl on the tray
Mo gbe okal- ori opon Ifa ki o le gbe mi ka 1 - ori
opon Ifa titi lai. (Ase.)
* D raw a line around the bowl clockwise
Mo ko - le yi o ka ki o le kg - le, yi me ka ki o le jeki
gmg yi mi ka ki o le jeki owo yi mi ka. (Ase.)
* E rase the line with a feather
Orin; Iba se o, mo juba e.
* S prinkle iyerosun on the floor
lie mo juba. (Iba se.)
* M ark a line from the center to the top of the tray
Mo la gna fun tororo ki o le la ona fun mi tororo ki o
le jeki gmg to gna yi wa s - gdg mi ki o le jeki owo tg
gna yi wa s - gdg mi. (Ase.)
* Stir the Iyerosun on the floor with a feather
Mo se il e bayi. (Ase.)
* Stir the iyerosun tray
Mo se opon bayi. (Ase.)
* T ap on the tray
A - gun se - o a - gun se. Bi akoko g-ori igi a se, a -
gun se -o, a - gun se. (Ase.)
Bi agbe ji a ma se, a - gun se - o, a - gun se. (Ase.)
Bi aluko ji a ma se, a - gun se - o, a - gun se. (Ase.)
Iba se (Name of Orisha ) Oba aiye ati Oba Orun iba yin
o. (Mo juba.)
Orunmila boru, Orunmila boye, Orunmila bosise.
* C lap hands three times
Adupe - o. (A dupe.)
* C ount out sixteen Ikin fromthebowl
A tun ka li asiwere ika owo re. (Ase.)
Iba Akoda. (Mo juba.)
Iba Aseda. (Mo juba.)
Iba Oluwo. (Mo juba.)
Iba Ojugbona. (Mo juba.)
Iba a ko ni li - fa. (Mo juba.)
Iba a te ni 1 - ere. (Mo juba.)
Iba a ko bayi. (Mo juba.)
Iba a te bayi. (Mo juba.)
Iba gbodipete. (Mo juba.)
Iba kukubole. (Mo juba.)
Iba okuta. (Mo juba.)
Iba loko. (Mo juba.)
Iba lodo. (Mo juba.)
* Replace the Ikin into the bowl
Oro kan so ko si awo n - ile oro kan so ko si agba n -
ile. (Ase.)
ORIN IKIN
Call; Ejiogbe a buru a boye akala o.
Response; A akala, a akala o.
Call; Oyeku meji a buru a boye akala o.
Response; A akala, a akala o.
ODUN IFA - JUNE
ORIKI F 'ODU MIMO
Omode 6 f oju b'Odu lasan; Agba 6 f oju b'Odu ni ofe;
Eni t'o ba f oju b'Odu yoo si d'awo. (Hein.)
A dia fun Orangun, He Ila, ti 6 gbalejo lati Ode Idan.
(Hein.)
Won ni b'o ba f oju b'alejo, orin ni ki 6 maa ko. (Hein.)
A f oju b'Odu, a rire 6 . (Hein.)
A f oju b'Odu, a rire. (Hein.)
Awa ma ma kuku f oju b'Odu. (Hein.)
A 6 ku mo. (Hein.)
A f oju b'Odu, a rire. (Hein.)
Aboru, aboye, ab osis e. (Ase.)
(Adimu Odu)
Yoruba Pronunciation
There are twenty-five letters in the Yoruba language, seven
vowels and eighteen consonants.
The vowels are A E £_ I 0 Q_U. The marks underthe letters
Land GLcreate different sounds from the letters E and 0 ,
without the marks. A ny mark under a Yoruba means you add
an H sound to the letter. Marks are found under E, 0 and
S.
The Yoruba alphabet with E nglish words that have the same
sound or intonations.
A (ah) Sounds like the A in A rk
B (bee) S ounds like the B in B ee
D (dee) Sounds like the D in D eal
E (ay) Sounds like the E in E ight
L (eh) Sounds like the E in E gg
F (fee) Sounds like the F in F eel
G (gi) Sounds like the G in G ive
G B No E nglish equivalent
H (hee) Sounds like the H in H ill
I (ee) Sounds like the I in B ee
J (gee) Sounds like the J in J eep
K (kee) Sounds like the K in Keep
L (lee) Sounds like the L in Leaf
M (mee)
Sounds
N (nee)
Sounds
0 (aw)
Sounds
Q_ (oh)
Sounds
P (pi)
Sounds
R (ree)
Sounds
S (cee)
Sounds
S_(Sh)
Sounds
T (tee)
Sounds
U (oo)
Sounds
W (we)
Sounds
Y (yee)
Sounds
like the M in M ilk
like the N in Nil
like the 0 in 0 dd
like the 0 in 0 h
like the P in P it
like the R in Read
like the S in S ea
like the S in Sheep
like the T in T ea
like the U in You
like the W in We
like the Y in Yield
Yoruba language is tonal meaning the relative pitch of letters
effects the meaning of the word. There are three basic
tones used in Yoruba that be described as do re mi or the
first three notes of the tempered scale. Normal speaking
voice would be re an accent slanting from left to right would
be m/and an accent slanting from right to left is do.